(FREE & 100% CONFIRMED)
Notice:
Please do Ajeogun first
before doing any of the below charm to make it work
perfectly for you.
Tude todaju
- Epo obo,
- iku ojia,
- igi nla
- ata ijosi
- eru alamo
- Aidan
ao gun gbogbo re mo ose dudu ao ma fi we gbogbo ide aye larawa loma tu Danu.
Tude Asina todaju
- Ewe tude
- Egbo tude
- Epo obo
- ose dudu
- epo pupa
- ori
oyin
ao gun gbogbo re month ose ti aba ti fe sun ni ale ojo alakoko ao fi epo rara ojo keji ao fi ori rara ojo keta ao fi oyin rara kato lore mawe odaju
OGUN ATOSI
- Bara
- Baaka
- egbojebo
- kanhun bilala
ao la bara si meji, ao ko gbogbo egusi inu re kuro, ao wa ge si wewe, ao ko sinu ikoko agbo, ao se gbogbo re lagbo pelu kanhun bilala na ti oba ti jina daadaa, eni na yio ma mu ilaji gaasi cup stainless laro ati laale
Ebe ati Asina awon Agba
- Eye alapandede
- ewe lapalapa funfun
- ose dudu
- igba olomori
- igbin kan
- kehin kehin tun tun
Eye alapandede ao gun po ma ewe lapalapa funfun ao wa popo ma ose dudu ao wa igba olomori ao wa fi igbin Kan si ao wa ko ose yi lelori ao ma buwe pelu kehin kehin tun tun odaju
Atude Asina odaju
- Eye ega
- egbo tude
- atare kan
- ogede omini
Ao Jo papo ao mafi je ogede omini die die.
IMULE FUN EYONU AYE
- Okete OOoye kan
- odindi atare kan
- schinap
Okete OOoye Kan, ao ge ori re ati iru re, ao ko ifun re jade, ao jo pelu odindi atare kan. Ao sun iyoku ara re, ao ge si 16, ao wa bo lori ina, ti o ba jina die, ohun ni ao fi gbe ipese ni aago kan oru. Ao fi ebu ti a jo yen die si, eyi to ku yen, ao fi schinap lo lekan na ti a ba ti gbe ipese yen ti a ti wole ni ao to lo
Ose Atude odaju
- Ata ijosi
- epo obo
- Ose dudu
Ata ijosi a o popo ma ose dudu ao ko sinu epo obo ao fi epo pupa para ao lore we ose yi ona yio si fun kia kia.
Eyonu ati Ibo Asiri
- Ikarahun igbin
- epo obo
- ose dudu
- omi agbon
- ankatifu funfun meji
- ike funfun
Ikarahun igbin ao lomo epo obo ti yio kuna dada ao popo ma ose dudu pelu omi agbon ao ra Ankatifu funfun meji ao KO ose yi sinu okan ao wa tun gbe sinu Ike funfun ankatifu elekeji lao mafi se kehin kehin tama fiwe
Ogun ulcer todaju
- Aidan bi meta
- roba totobi kan
- ose dudu
- Aidan bi meta
eo wafi obe ge isu arare eo so iyoku nu eo ko si inu roba kan totobi niwan ba eo wa ko ose bi oni 50 naira eo da meji idakan oseyi eo kosi eo wa bu omisi eo gbe kale di ojo keji eo wa mafi tele inu lararo keto jehun eo tun ma mun die die teba felosun.
Atike Itaja
- Ori Agiliti
- ori aparo
- ori musu eyi toni irun
- Ewe ajade
- eru alamo
- koro owu
- oyin
Ori Agiliti, ori aparo, ori olonginni eyi toni irun, Ewe ajade, eru alamo, koro owu kopo die, oyin bi sibi meji ao gun gbogbo re sakasaka ao mafi lararo.
OSE AWURE
- Ewe tagiri
- ewe sawerepepe
- ewe imi esu
- ose dudu
ao gun ao fi ori popo man ose dudu ao ma fi we
IDAKOLE (Amokole)
- Ododo Asunwon Oyinbo
- kaun die
ao sa ko gbe daada, ao lo kahun die pelu e, ao ma fi ogi gbigbona mu ni sibi kan laraaro.
OGUN GIRI OMODE
- Igi taba tutu
- adin eyan
- Tagiri
ao jo po ao ma bu sinu adin eyan omona yio mala, Giri koni yo omo na lenu ma.
Ebe/imule awon Agba todaju
- Alubosa elewe tutu
- kopo die
- ose dudu
- eyin adie
- igba olomori
ao gun dada ao popo ma ose dudu ao wa eyin adie Oojo ao do gbon fo lori die ti korofo eyin yi konibaje ao jo omi eyin naa sinu ose yi ao tun gun dada ao wa igba olomori ao ko ose yi si ninu ao wa fi korofo eyin yi gun ose yi lori logan gan ibi ti ati fo eyin na ni yio koju sinu ose, ao ti koko dogban fowo jin ibibe kato fi eyin na gun ki korofo eyin na maba fo. Ao ma buwe nigba toba wuwa.
KOKORO OMUN OBINRIN
- Ewe Egele
- ireke
- ogede wewe ti ko gbo
- eru
- epo pupa die
ao fi omi orombo si ao waa se ao maa fi we omu naa ao si maa mun ni ibe
ISOYE
- ewe oniyemeye
- eye awoko
- odidi atare kan
- oyin igan gidi
a o mu ewe oniyemeye, eye awoko, odidi atare kan, a o Jo po, dada , a o da sinu oyin igan gidi, a o ma la
ASIRI BIBO
- Ewe imi esu
- Ose dudu
Ao gun po ao fi eje aguntan toti bi omo ri po ose naa daadaa.
AFUNJE
- Irun Abe
- ekana owo mewewa
- run Ori die
- Awo Ewure dudu,
- Ewe Amunimuye,
- ese mewewa,
- irun Ipenpeju die
ao jo pelu Odindi ataare kan, ao maa fun enia je.
AJEOGUN
- Ewe Ela
- Atelewo elegede
- oko ataare kan
- ewe ajeobale
- epo obo
ao jopo ao fi sin gbere yii orun owo mejeji ka .
Ewe Aje o
ReplyDeletePls sir,what's the meaning of Ogun ajeogun
ReplyDeletebaba ewe aje oooooo. mo ko ogun yin jade , mo fe gba iyonda kin tose. sugbon maa pe yin lori aago.
ReplyDeletee jọ̀wọ́ mofé oògùn ìdákolètódájú
ReplyDeleteBABA eweje ejo eda yo mi ni enu
ReplyDeleteEwe ama je o, ejo sir see ajeogun ajesara Tabi ajesinu ni mobere fun,ti mi o ni sin gbere
ReplyDeleteEnter your comment...ewe ama je o , aboruboye o
ReplyDeleteEse sir baba ewe you maa je oo
ReplyDeleteEseoo baba adupe o
ReplyDeleteOGBO ATO O BABA
ReplyDelete